Jónà 2:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Omi yí mi káàkiri, àní títí dé ọkàn;ibú yí mi káàkiri,a fi koríko odò wé mi lórí.

Jónà 2

Jónà 2:1-10