Jeremáyà 49:36 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èmi yóò mú kí afẹ́fẹ́ orígun mẹ́rẹ̀ẹ̀rinàgbáyé lòdì sí Élámù.Èmi yóò tú wọn ká sí ìpín afẹ́fẹ́ mẹ́rinàti pé, kò sí orílẹ̀ èdè tí ilẹ̀ àjèjì Élámù kò ní lọ.

Jeremáyà 49

Jeremáyà 49:26-39