Jẹ́nẹ́sísì 47:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jósẹ́fù sì pèṣè oúnjẹ fún baba rẹ̀ àti àwọn arákùnrin rẹ̀ àti gbogbo ìdílé baba rẹ̀ gẹ́gẹ́ bi iye àwọn ọmọ wọn.

Jẹ́nẹ́sísì 47

Jẹ́nẹ́sísì 47:10-16