Jẹ́nẹ́sísì 47:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Joṣẹ́fù sì fi baba rẹ̀ àti àwọn arákùnrin rẹ̀ sí ilẹ̀ Éjíbítì, ó sì fún wọn ní ohun-ìní ní ibi tí ó dára jù ní ilẹ̀ náà, ní agbégbé Ráméṣéṣì bí Fáráò ti pàṣẹ.

Jẹ́nẹ́sísì 47

Jẹ́nẹ́sísì 47:6-12