Jẹ́nẹ́sísì 47:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jósẹ́fù lọ sọ fún Fáráò pé, “Baba mi àti àwọn arákùnrin mi, pẹ̀lú agbo ẹran, agbo màlúù àti ohun gbogbo tí wọ́n ní, ti dé láti ilẹ̀ Kénánì, wọ́n sì ti wà ní ilẹ̀ Gósénì báyìí.”

Jẹ́nẹ́sísì 47

Jẹ́nẹ́sísì 47:1-4