Jẹ́nẹ́sísì 40:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ni ọ̀kọ̀ọ̀kan àwọn ọkùnrin méjèèjì náà-olórí agbọ́tí àti olórí alásè lá àlá, ní òru kan náà, àlá kọ̀ọ̀kan sì ní ìtumọ̀ tirẹ̀.

Jẹ́nẹ́sísì 40

Jẹ́nẹ́sísì 40:1-15