Jẹ́nẹ́sísì 40:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Olórí ẹ̀sọ́ sì yan Jósẹ́fù láti máa ṣe ìránṣẹ́ wọn.Lẹ́yìn ìgbà tí wọ́n ti wà ní ìhámọ́ fún ìgbà díẹ̀.

Jẹ́nẹ́sísì 40

Jẹ́nẹ́sísì 40:1-6