Jẹ́nẹ́sísì 36:31 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwọn wọ̀nyí ni àwọn ọba tí ó ti jẹ ní Édómù kí ó tó di pé a ń jẹ ọba ní Ísírẹ́lì rárá:

Jẹ́nẹ́sísì 36

Jẹ́nẹ́sísì 36:29-35