Jẹ́nẹ́sísì 36:30 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Dísónì Éṣérì, àti Díṣánì. Àwọn ni olórí ìdílé àwọn ará Órì gẹ́gẹ́ bí ìpín wọn ní ilẹ̀ Ṣéírì.

Jẹ́nẹ́sísì 36

Jẹ́nẹ́sísì 36:21-39