Jẹ́nẹ́sísì 36:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwọn ọmọ Rúélì:Náhátì, Ṣérà, Ṣámà àti Mísà. Àwọn ni ọmọ-ọmọ Báṣémátì aya Ísọ̀.

Jẹ́nẹ́sísì 36

Jẹ́nẹ́sísì 36:3-15