Jẹ́nẹ́sísì 36:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Élífásì ọmọ Ísọ̀ sì tún ní àlè tí a ń pè ní Tímúnà pẹ̀lú, òun ló bí Ámálékì fún un. Wọ̀nyí ni àwọn ọmọ-ọmọ Ádà aya Ísọ̀.

Jẹ́nẹ́sísì 36

Jẹ́nẹ́sísì 36:11-14