Jẹ́nẹ́sísì 35:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Lẹ́yìn tí Jákọ́bù padà dé láti Padani-Árámù, Ọlọ́run tún fara hàn-án, ó sì súre fún un.

Jẹ́nẹ́sísì 35

Jẹ́nẹ́sísì 35:1-18