Jẹ́nẹ́sísì 35:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kò pẹ́ lẹ́yìn èyí ni Dèbórà, olùtọ́jú Rèbékà kú, a sì sin-ín sábẹ́ igi Óàkù ní ìsàlẹ̀ Bẹ́tẹ́lì: Nítorí náà a sọ ọ́ ní Aloni-Bákútì (Óákù Ẹkún).

Jẹ́nẹ́sísì 35

Jẹ́nẹ́sísì 35:1-16