Ẹ́sírà 7:19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kó gbogbo ohun èlò tí a fi sí ìkáwọ́ rẹ fún Ọlọ́run Jérúsálẹ́mù fún ìsìn nínú tẹ́ḿpìlì Ọlọ́run rẹ.

Ẹ́sírà 7

Ẹ́sírà 7:12-26