Ẹ́sírà 7:18 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìwọ àti àwọn Júù arákùnrin rẹ lè fi èyí tó kù fàdákà àti wúrà ṣe ohunkóhun tí ó bá dára lójú yín, ní ìbámu pẹ̀lú ìfẹ́ Ọlọ́run yín.

Ẹ́sírà 7

Ẹ́sírà 7:16-25