Ékísódù 12:1-3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Olúwa sọ fún Mósè àti Árónì ni ilẹ̀ Éjíbítì pé,

2. “Osù yìí ni yóò jẹ́ osù àkọ́kọ́ fún yín oṣù àkọ́kọ́ nínú ọdún yín.

3. Sọ fún gbogbo àwọn ènìyàn Ísírẹ́lì pé ni ọjọ́ kẹwàá oṣù yìí, ọkùnrin kọ̀ọ̀kan yóò mú ọ̀dọ́ àgùntàn kọ̀ọ̀kan fún ìdílé rẹ̀, ọ̀kan fún agbo ilé kọ̀ọ̀kan.

Ékísódù 12