Ékísódù 12:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Sọ fún gbogbo àwọn ènìyàn Ísírẹ́lì pé ni ọjọ́ kẹwàá oṣù yìí, ọkùnrin kọ̀ọ̀kan yóò mú ọ̀dọ́ àgùntàn kọ̀ọ̀kan fún ìdílé rẹ̀, ọ̀kan fún agbo ilé kọ̀ọ̀kan.

Ékísódù 12

Ékísódù 12:1-4