Éfésù 3:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àti láti mú kí gbogbo ènìyàn rí ohun tí iṣẹ́ ìríjú ohun ìjìnlẹ̀ náà jásí, èyí tí a ti fi pamọ́ láti ayébáyé nínú Ọlọ́run, ẹni tí o dá ohun gbogbo nípa Jésù Kírísítì:

Éfésù 3

Éfésù 3:1-13