Éfésù 3:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Fún èmi tí o kéré jùlọ nínú gbogbo àwọn ènìyàn mímọ́, ní a fi oore ọ̀fẹ́ yìí fún, láti wàásù àwámárídi ọ̀rọ̀ Kírísítì fún àwọn aláìkọlà;

Éfésù 3

Éfésù 3:2-18