Deutarónómì 34:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Mósè jẹ́ ẹni ọgọ́fà ọdún nígbà tí ó kú, síbẹ̀ ojú rẹ̀ kò ṣe bàìbàì bẹ́ẹ̀ ni agbára rẹ̀ kò dínkù.

Deutarónómì 34

Deutarónómì 34:3-9