Deutarónómì 34:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó sì sin ín nínú àfonífojì ní ilẹ̀ Móábù, tí ó kọjú sí Béhì-Péórì, ṣùgbọ́n títí di òní yìí, kò sí ẹnì kan tí ó mọ ibi tí ibojì i rẹ̀ wà.

Deutarónómì 34

Deutarónómì 34:1-12