Deutarónómì 28:44 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Yóò yà ọ́, ṣùgbọ́n o kì yóò yà á, òun ni yóò jẹ́ orí, ìwọ yóò jẹ́ ìrù.

Deutarónómì 28

Deutarónómì 28:36-54