Àwọn Hébérù 13:22 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èmi sì ń bẹ̀ yín ará, ẹ gbà ọ̀rọ̀ ìyànjú mi; nítorí ìwé kukuru ni mo kọ sí yín.

Àwọn Hébérù 13

Àwọn Hébérù 13:16-25