Àwọn Hébérù 13:21 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kí ó mú yín pé nínú iṣẹ́ rere gbogbo láti ṣe ìfẹ́ rẹ̀, kí ó máa ṣiṣẹ ohun tí i ṣe ìtẹ́wọ́gbà níwájú rẹ̀ nínú yín nípasẹ̀ Jésù Kírísítì; ẹni tí ògo wà fún láé àti láéláé. Àmín

Àwọn Hébérù 13

Àwọn Hébérù 13:20-25