Àwọn ènìyàn yóò rìn kiri láti òkun dé òkunwọn yóò sì máa rìn ká láti gúṣù sí àríwá,wọn yóò máa wá ọ̀rọ̀ Olúwaṣùgbọ́n wọn kì yóò rí i.