Ámósì 2:15-16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

15. tafàtafà kì yóò dúró lórí ẹsẹ̀ rẹ̀bẹ́ẹ̀ ni ẹni tí ó gún ẹṣinkì yóò gba ẹ̀mí ara rẹ̀ là

16. àní jagunjagun tí ó gbóyà jùlọyóò sálọ ní ìhòòhò ní ọjọ́ náà,”ni Olúwa wí.

Ámósì 2