Ámósì 3:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹ gbọ́ ọ̀rọ̀ tí Ọlọ́run ti sọ nípa rẹ̀, ẹ̀yin ènìyàn Ísírẹ́lì nípa àwọn ìdílé tí mo mú jáde láti Éjíbítì:

Ámósì 3

Ámósì 3:1-4