Àìsáyà 7:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Jẹ́ kí a kọlu Júdà; jẹ́ kí a fà á ya pẹ́rẹpẹ̀rẹ, kí a sì pín in láàrin ara wa, kí a sì fi ọmọ Tábẹ́lì jọba lóríi rẹ̀.”

Àìsáyà 7

Àìsáyà 7:1-14