Àìsáyà 6:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nípa ìró ohùn un wọn, òpó ìlẹ̀kùn àti gbogbo ògiri ilé náà sì mì tìtì, gbogbo inú tẹ́ḿpìlì sì kún fún èéfín.

Àìsáyà 6

Àìsáyà 6:3-8