Àìsáyà 6:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wọ́n sì ń kọ sí ara wọn wí pé:“Mímọ́, mímọ́, mímọ́ ni Olúwa àwọn ọmọ ogungbogbo ayé kún fún ògo rẹ̀.”

Àìsáyà 6

Àìsáyà 6:1-6