Àìsáyà 52:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Olúwa yóò sí apá mímọ́ rẹ̀ sílẹ̀ní ojú gbogbo orílẹ̀ èdè,àti gbogbo òpin ilẹ̀ ayé yóò ríìgbàlà Ọlọ́run wa.

Àìsáyà 52

Àìsáyà 52:9-12