Àìsáyà 5:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó tu ilẹ̀ rẹ̀, ó ṣa òkúta ibẹ̀ kúròó sì gbin àyànfẹ́ àjàrà síi.Ó kọ́ ilé-ìṣọ́ sí inú un rẹ̀ó sì ṣe ìfúntí kan ṣíbẹ̀ pẹ̀lú.Lẹ́yìn náà, ó ń retí èso àjàrà dáradára,ṣùgbọn èṣo búburú ni ó ti ibẹ̀ wá.

Àìsáyà 5

Àìsáyà 5:1-9