Àìsáyà 5:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èmi yóò kọrin fún ẹni tí mo fẹ́rànorin kan nípa ọgbà-àjàrà rẹ̀;Olùfẹ́ẹ̀ mi ní ọgbà-àjàrà kanní ẹ̀gbẹ́ òkè ẹlẹ́tù lójú.

Àìsáyà 5

Àìsáyà 5:1-3