Àìsáyà 40:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ohùn ẹnìkan tí ń pè:“Nínú ihà ẹ pèṣèọ̀nà sílẹ̀ fún Olúwa:ṣe é kí ó tọ́ ní ihàòpópónà fún Ọlọ́run wa.

Àìsáyà 40

Àìsáyà 40:1-12