Àìsáyà 40:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Sọ̀rọ̀ pẹ̀lẹ́pẹ̀lẹ́ fún Jérúsálẹ́mùkí o sì kéde fún unpé iṣẹ́ àṣekára rẹ̀ ti parí,pé à ti san gbésè ẹ̀ṣẹ̀ rẹ̀,pé ó ti rí i gbà láti ọwọ́ Olúwaìlọ́po méjì fún gbogbo ẹ̀ṣẹ̀ rẹ̀.

Àìsáyà 40

Àìsáyà 40:1-3