Àìsáyà 30:21 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí o bá yí sápá ọ̀tún tàbí apá òsi, etí rẹ yóò máa gbọ́ ohùn kan lẹ́yìn rẹ, wí pé, “Ọ̀nà nìyìí, máa rìn nínú rẹ̀.”

Àìsáyà 30

Àìsáyà 30:16-25