Àìsáyà 16:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwa ti gbọ́ nípa ìgbéraga Móábù—Wábiwọ́sí ìgbéraga rẹ̀ àti fùlenge fùlenge,gààrùu rẹ̀ àti àfojúdi rẹ̀—ṣùgbọ́n ìfọ́nnu rẹ̀ jẹ́ ìmúlẹ̀mófo.

Àìsáyà 16

Àìsáyà 16:1-9