2 Kọ́ríńtì 13:11-14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

11. Ní àkótan, ará ó dì gbòóṣe, ẹ ṣe àtúnse ọ̀nà yín, ẹ tújúká, ẹ jẹ́ onínúkan, ẹ máa wà ní àlàáfíà, Ọlọ́run ìfẹ́ àti ti àlàáfíà yóò wà pẹ̀lú yín.

12. Ẹ fi ìfẹnukonu mímọ́ kí ara yín.

13. Gbogbo àwọn ènìyàn mímọ́ kí yín.

14. Oore ọ̀fẹ́ Jésù Kírísítì Olúwa, àti ìfẹ́ Ọlọ́run, àti ìdàpọ̀ ti Èmí Mímọ́, kí ó wà pẹ̀lú gbogbo yín. (Àmín).

2 Kọ́ríńtì 13