2 Kọ́ríńtì 13:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní àkótan, ará ó dì gbòóṣe, ẹ ṣe àtúnse ọ̀nà yín, ẹ tújúká, ẹ jẹ́ onínúkan, ẹ máa wà ní àlàáfíà, Ọlọ́run ìfẹ́ àti ti àlàáfíà yóò wà pẹ̀lú yín.

2 Kọ́ríńtì 13

2 Kọ́ríńtì 13:1-12