1 Ọba 8:51 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

nítorí ènìyàn rẹ àti ìní rẹ ni wọ́n, àwọn ẹni tí ìwọ ti mú ti Éjíbítì jáde wá, láti inú irin ìléru.

1 Ọba 8

1 Ọba 8:48-53