1 Ọba 8:50 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kí o sì dáríjìn àwọn ènìyàn rẹ, tí wọ́n ti dẹ́ṣẹ̀ sí ọ; dárí gbogbo ìrékọjá wọn tí wọ́n ṣe sí ọ jì, kí o sì bá àwọn tí ó kó wọn ní ìgbèkùn lọ wí, kí wọn kí ó lè ṣàánú fún wọn;

1 Ọba 8

1 Ọba 8:43-57