1 Ọba 18:33 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó sì to igi náà dáradára, ó sì ké ẹgbọ̀rọ̀ akọ màlúù náà wẹ́wẹ́, ó sì tò ó sórí igi. Nígbà náà ni ó sì wí fún wọn wí pé, “Ẹ fi omi kún ìkòkò mẹ́rin, kí ẹ sì tun sórí ẹbọ sísun àti sórí igi náà.”

1 Ọba 18

1 Ọba 18:25-36