1 Ọba 18:32 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó sì tẹ́ pẹpẹ pẹ̀lú àwọn òkúta wọ̀nyí ní orúkọ Olúwa, ó sì wa yàrá yí pẹpẹ náà ká, tí ó lè gba ìwọ̀n òṣùwọ̀n irúgbìn méjì.

1 Ọba 18

1 Ọba 18:26-36