1 Ọba 14:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Lọ, sọ fún Jéróbóámù pé báyìí ni Olúwa Ọlọ́run Ísírẹ́lì wí; Èmi sì gbé ọ ga láti inú àwọn ènìyàn, mo sì fi ọ́ jẹ olórì lórí Ísírẹ́lì ènìyàn mi.

1 Ọba 14

1 Ọba 14:5-12