1 Kọ́ríńtì 13:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

A máa faradà ohun gbogbo sí òtítọ́, a máa gba ohun gbógbo gbọ́, a máa retí ohun gbogbo, a máa fàyàrán ohun gbogbo.

1 Kọ́ríńtì 13

1 Kọ́ríńtì 13:5-13