1 Kọ́ríńtì 13:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Inú ìfẹ́ kì í dùn sí àìsòótọ́. Ṣùgbọ́n inú rẹ̀ a máa dùn nígbà gbogbo sí òtítọ́.

1 Kọ́ríńtì 13

1 Kọ́ríńtì 13:1-11