1 Kíróníkà 16:42-43 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

42. Hémánì àti Jédútúnì ni wọ́n dúró fún fifọn ìpè àti Ṣíḿibálì àti fún títa ohun èlò yòókù fún orin yíyàsọ́tọ̀. Àwọn ọmọ Jédútúnì wà ní ipò dídúró ní ẹnu-ọ̀nà.

43. Nígbà náà gbogbo àwọn ènìyàn kúrò, olúkúlùkù sí ilé láti lọ bùkún ìdílé Rẹ̀

1 Kíróníkà 16