Hémánì àti Jédútúnì ni wọ́n dúró fún fifọn ìpè àti Ṣíḿibálì àti fún títa ohun èlò yòókù fún orin yíyàsọ́tọ̀. Àwọn ọmọ Jédútúnì wà ní ipò dídúró ní ẹnu-ọ̀nà.