Tit 3:15 Yorùbá Bibeli (YCE)

Gbogbo awọn ti mbẹ lọdọ mi kí ọ. Kí awọn ti o fẹ wa ninu igbagbọ́. Ki ore-ọfẹ ki o wà pẹlu gbogbo nyin. Amin.

Tit 3

Tit 3:5-15