Sek 9:16 Yorùbá Bibeli (YCE)

Oluwa Ọlọrun wọn yio si gbà wọn là li ọjọ na bi agbo enia rẹ̀: nitori nwọn o dabi awọn okuta ade, ti a gbe soke bi àmi lori ilẹ rẹ̀.

Sek 9

Sek 9:6-17